Lyrics

(Yo-) Yeah Take it or not, I'm blessed Ṣẹ gbọ o? Oh, yes And no son of man can take my joy away Wetin be my own no go pass me by Ẹkùn ati òṣì, bye-bye Tẹ ba ro pe ẹ n ṣe mi Atanda Ara yin lẹ n ṣe Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ The horror mọ wọn lọwọ K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?" Ni mo fi sun ṣòkòtò Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ And e no get where e touch (aje, aje) Ladugbo yin emi l'ọn gbọ Orin wa l'ọn n jẹ nigboro Kiamọsa ni ko tete Ma tori mi lọ jẹ gbese Anoti, anoti, allele Ẹni wuwa epe lo ma gbepe Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè Psycho pọ lode Àwọn le mọ le ṣe Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila Ara rẹ loo pa Itakun to ni kerin ma wọ'dò, to ni kerin ma wọ'dò Toun terin ni wọn jọ lọ (ayan o) Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ The horror mọ wọn lọwọ K'ọn ma ba a sọ pe, "Temi bawo?" Ni mo fi sun ṣòkòtò Ẹ ma lu kan pa te ba fọmọwọmọ And e no get where e touch (aje, aje) Ladugbo yin emi l'ọn gbọ Orin wa l'ọn n jẹ nigboro Kiamọsa ni ko tete Ma tori mi lọ jẹ gbese Anoti, anoti, allele Ẹni wuwa epe lo ma gbepe Ọmọ araye le ya'yan ni wèrè Psycho pọ lode Àwọn le mọ le ṣe Ẹni to mon eniyan lo n ṣ'ese eniyan o Afopina to loun o pa fitila, to loun o pa fitila Ara rẹ loo pa Itakun to ni kerin ma wọ'dò, o ni kerin ma wọ'dò Toun terin ni wọn jọ lọ (Yo Dips)
Writer(s): Olawale Adibe, Balogun Oluwakayode Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out