Top Songs By Dami Drizzy
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Dami Luchi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Dami Luchi
Songwriter
Lyrics
Mo mo
Ah ah ah, ah ah ah, ah ah ahhh (xcluso, the sound maker)
Eh eh eh, eh eh eh, eh eh ehhh
Motun ti de gege bi mo se n de (xcluso on the beat)
Mo ti be olodumare ki baba ba mi se
Mo lo irinajo, awon ota won o fe ki n de
Sugbon ifa olokun baba ti ba mi se
Mo mo pe orin ti mo fe ko yii
Won ma gb'ogun
Sugbon eni logo, ko le salailogun
Eni n lo lasan won mu okuta gan won tun so fun
Mo mo pe ifa a ba mi segun
Bi erin ba ji erin a ki olu'gbo
Bi efon ba'ji efon a ki olu odan
Erin to ba ji ti ko ba k'olu'gbo
Beeni efon to ba ji ti ko ba k'olu odan
Awon mejeji won fi ara won fi kasa
Mi ba tija wa beeni mi ba tere wa
Ti won ba ni isoro awa naa na ma saba
Awon to n fi oruko mii gba yin le gan won ni ifa
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi'ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi'ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso
Ebe ni mo be apari inu mi
Ko ma se je ki n rogun elenini (xcluso, the soundmaker)
Ki awon kan ko ma se je ipin mi (xcluso on the beat)
Ki omo araye ki won ma se damu mi
Ire ni ki n ma ri, baba ma je n ri ibi (xcluso on the beat)
Oju to ma ri ire ko le se alai ri ibi
Ti won ba wa fi ifa buru baba ma je won o ri mi
Baba gbo adura mi ko to su mi
Ope fun olorun oo, oba toto
Iyin ye e o, odumare
Ogo ye oo orunmila
Iyin ye oo asiwaju rere
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi'ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan
Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso (oh)
Ope fun olorun oo, oba toto (xcluso the sound maker)
Iyin ye e o, odumare (eh eh)
Ogo ye oo orunmila (xcluso on the beat)
Iyin ye oo asiwaju rere
Lyrics powered by www.musixmatch.com